Léfítíkù 2:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 “‘Tí ẹnì* kan bá fẹ́ mú ọrẹ ọkà+ wá fún Jèhófà, kó jẹ́ ìyẹ̀fun tó kúnná, kó da òróró sórí rẹ̀, kó sì fi oje igi tùràrí sórí rẹ̀.+ Léfítíkù 2:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 “‘Ẹ má ṣe mú ọrẹ ọkà kankan tó ní ìwúkàrà+ wá fún Jèhófà, ẹ ò sì gbọ́dọ̀ mú kí àpòrọ́ kíkan tàbí oyin èyíkéyìí rú èéfín bí ọrẹ àfinásun sí Jèhófà.
2 “‘Tí ẹnì* kan bá fẹ́ mú ọrẹ ọkà+ wá fún Jèhófà, kó jẹ́ ìyẹ̀fun tó kúnná, kó da òróró sórí rẹ̀, kó sì fi oje igi tùràrí sórí rẹ̀.+
11 “‘Ẹ má ṣe mú ọrẹ ọkà kankan tó ní ìwúkàrà+ wá fún Jèhófà, ẹ ò sì gbọ́dọ̀ mú kí àpòrọ́ kíkan tàbí oyin èyíkéyìí rú èéfín bí ọrẹ àfinásun sí Jèhófà.