Ẹ́kísódù 12:38 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 38 Oríṣiríṣi èèyàn tó pọ̀ rẹpẹtẹ*+ ló tún bá wọn lọ, pẹ̀lú àwọn agbo ẹran àti ọ̀wọ́ ẹran, ọ̀pọ̀ rẹpẹtẹ ẹran ọ̀sìn. Nọ́ńbà 11:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Onírúurú èèyàn*+ tó wà láàárín wọn bá bẹ̀rẹ̀ sí í fi ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ ọkàn+ wọn hàn, àwọn ọmọ Ísírẹ́lì náà tún wá ń sunkún, wọ́n sì ń sọ pé: “Ta ló máa fún wa ní ẹran jẹ?+
38 Oríṣiríṣi èèyàn tó pọ̀ rẹpẹtẹ*+ ló tún bá wọn lọ, pẹ̀lú àwọn agbo ẹran àti ọ̀wọ́ ẹran, ọ̀pọ̀ rẹpẹtẹ ẹran ọ̀sìn.
4 Onírúurú èèyàn*+ tó wà láàárín wọn bá bẹ̀rẹ̀ sí í fi ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ ọkàn+ wọn hàn, àwọn ọmọ Ísírẹ́lì náà tún wá ń sunkún, wọ́n sì ń sọ pé: “Ta ló máa fún wa ní ẹran jẹ?+