ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 78:18
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 Wọ́n pe Ọlọ́run níjà* nínú ọkàn wọn,+

      Bí wọ́n ṣe ń béèrè oúnjẹ tí ọkàn wọn fà sí.*

  • Sáàmù 78:22
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 22 Torí pé wọn ò ní ìgbàgbọ́ nínú Ọlọ́run;+

      Wọn ò gbẹ́kẹ̀ lé e pé ó lágbára láti gbà wọ́n là.

  • Sáàmù 106:14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 Wọ́n jẹ́ kí ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ gbà wọ́n lọ́kàn ní aginjù;+

      Wọ́n dán Ọlọ́run wò ní aṣálẹ̀.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́