Ẹ́kísódù 20:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 “O ò gbọ́dọ̀ lo orúkọ Jèhófà Ọlọ́run rẹ lọ́nà tí kò tọ́,+ torí Jèhófà kò ní ṣàìfi ìyà jẹ ẹni tó bá lo orúkọ Rẹ̀ lọ́nà tí kò tọ́.+ Ẹ́kísódù 22:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 “O ò gbọ́dọ̀ sọ̀rọ̀ òdì sí* Ọlọ́run+ tàbí kí o sọ̀rọ̀ òdì sí ìjòyè* nínú àwọn èèyàn rẹ.+ Léfítíkù 19:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ẹ ò gbọ́dọ̀ fi orúkọ mi búra èké,+ kí ẹ má bàa sọ orúkọ Ọlọ́run yín di aláìmọ́. Èmi ni Jèhófà.
7 “O ò gbọ́dọ̀ lo orúkọ Jèhófà Ọlọ́run rẹ lọ́nà tí kò tọ́,+ torí Jèhófà kò ní ṣàìfi ìyà jẹ ẹni tó bá lo orúkọ Rẹ̀ lọ́nà tí kò tọ́.+