Léfítíkù 25:43 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 43 Má hùwà ìkà sí i,+ kí o sì máa bẹ̀rù Ọlọ́run rẹ.+ Òwe 1:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ìbẹ̀rù* Jèhófà ni ìbẹ̀rẹ̀ ìmọ̀.+ Àwọn òmùgọ̀ ni kì í ka ọgbọ́n àti ìbáwí sí.+ Òwe 8:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ìbẹ̀rù Jèhófà ni ìkórìíra ohun búburú.+ Mo kórìíra ìṣefọ́nńté àti ìgbéraga+ àti ọ̀nà ibi àti ọ̀rọ̀ àyídáyidà.+
13 Ìbẹ̀rù Jèhófà ni ìkórìíra ohun búburú.+ Mo kórìíra ìṣefọ́nńté àti ìgbéraga+ àti ọ̀nà ibi àti ọ̀rọ̀ àyídáyidà.+