Léfítíkù 25:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ẹnì kankan nínú yín ò gbọ́dọ̀ rẹ́ ọmọnìkejì rẹ̀ jẹ,+ ẹ sì gbọ́dọ̀ bẹ̀rù Ọlọ́run yín,+ torí èmi ni Jèhófà Ọlọ́run yín.+ Oníwàásù 12:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Òpin ọ̀rọ̀ náà, lẹ́yìn gbígbọ́ gbogbo rẹ̀ ni pé: Bẹ̀rù Ọlọ́run tòótọ́,+ kí o sì pa àwọn àṣẹ rẹ̀ mọ́,+ nítorí èyí ni gbogbo ojúṣe èèyàn.+
17 Ẹnì kankan nínú yín ò gbọ́dọ̀ rẹ́ ọmọnìkejì rẹ̀ jẹ,+ ẹ sì gbọ́dọ̀ bẹ̀rù Ọlọ́run yín,+ torí èmi ni Jèhófà Ọlọ́run yín.+
13 Òpin ọ̀rọ̀ náà, lẹ́yìn gbígbọ́ gbogbo rẹ̀ ni pé: Bẹ̀rù Ọlọ́run tòótọ́,+ kí o sì pa àwọn àṣẹ rẹ̀ mọ́,+ nítorí èyí ni gbogbo ojúṣe èèyàn.+