Jóòbù 28:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Ó sì sọ fún èèyàn pé: ‘Wò ó! Ìbẹ̀rù Jèhófà ni ọgbọ́n,+Yíyẹra fún ìwà burúkú sì ni òye.’”+ Sáàmù 111:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ìbẹ̀rù Jèhófà ni ìbẹ̀rẹ̀ ọgbọ́n.+ ש [Sínì] Gbogbo àwọn tó ń pa àwọn àṣẹ rẹ̀* mọ́ ní òye tó jinlẹ̀ gan-an.+ ת [Tọ́ọ̀] Ìyìn rẹ̀ wà títí láé. Òwe 1:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ìbẹ̀rù* Jèhófà ni ìbẹ̀rẹ̀ ìmọ̀.+ Àwọn òmùgọ̀ ni kì í ka ọgbọ́n àti ìbáwí sí.+
10 Ìbẹ̀rù Jèhófà ni ìbẹ̀rẹ̀ ọgbọ́n.+ ש [Sínì] Gbogbo àwọn tó ń pa àwọn àṣẹ rẹ̀* mọ́ ní òye tó jinlẹ̀ gan-an.+ ת [Tọ́ọ̀] Ìyìn rẹ̀ wà títí láé.