Jóòbù 28:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Ó sì sọ fún èèyàn pé: ‘Wò ó! Ìbẹ̀rù Jèhófà ni ọgbọ́n,+Yíyẹra fún ìwà burúkú sì ni òye.’”+ Òwe 1:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ìbẹ̀rù* Jèhófà ni ìbẹ̀rẹ̀ ìmọ̀.+ Àwọn òmùgọ̀ ni kì í ka ọgbọ́n àti ìbáwí sí.+ Oníwàásù 12:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Òpin ọ̀rọ̀ náà, lẹ́yìn gbígbọ́ gbogbo rẹ̀ ni pé: Bẹ̀rù Ọlọ́run tòótọ́,+ kí o sì pa àwọn àṣẹ rẹ̀ mọ́,+ nítorí èyí ni gbogbo ojúṣe èèyàn.+
13 Òpin ọ̀rọ̀ náà, lẹ́yìn gbígbọ́ gbogbo rẹ̀ ni pé: Bẹ̀rù Ọlọ́run tòótọ́,+ kí o sì pa àwọn àṣẹ rẹ̀ mọ́,+ nítorí èyí ni gbogbo ojúṣe èèyàn.+