Diutarónómì 12:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Tí ẹ bá ti sọdá Jọ́dánì,+ tí ẹ sì wá ń gbé ní ilẹ̀ tí Jèhófà Ọlọ́run yín fẹ́ fún yín pé kó di tiyín, ó dájú pé ó máa mú kí ẹ sinmi lọ́wọ́ gbogbo àwọn ọ̀tá yín tó yí yín ká, ẹ ó sì máa gbé láìséwu.+ Sáàmù 4:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Màá dùbúlẹ̀, màá sì sùn ní àlàáfíà,+Nítorí ìwọ nìkan, Jèhófà, ló ń mú kí n máa gbé láìséwu.+ Òwe 1:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 Àmọ́ ẹni tó ń fetí sí mi á máa gbé lábẹ́ ààbò+Ìbẹ̀rù àjálù kò sì ní yọ ọ́ lẹ́nu.”+
10 Tí ẹ bá ti sọdá Jọ́dánì,+ tí ẹ sì wá ń gbé ní ilẹ̀ tí Jèhófà Ọlọ́run yín fẹ́ fún yín pé kó di tiyín, ó dájú pé ó máa mú kí ẹ sinmi lọ́wọ́ gbogbo àwọn ọ̀tá yín tó yí yín ká, ẹ ó sì máa gbé láìséwu.+