Sáàmù 3:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Màá dùbúlẹ̀, màá sùn;Màá sì jí ní àlàáfíà,Nítorí Jèhófà ń tì mí lẹ́yìn.+ Òwe 3:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Nígbà tí o bá dùbúlẹ̀, ẹ̀rù ò ní bà ọ́;+Wàá sùn, oorun rẹ á sì dùn mọ́ ọ.+ Òwe 3:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Nítorí Jèhófà yóò jẹ́ ìgbọ́kànlé rẹ;+Kò ní jẹ́ kí ẹsẹ̀ rẹ kó sí pańpẹ́.+