Sáàmù 4:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Màá dùbúlẹ̀, màá sì sùn ní àlàáfíà,+Nítorí ìwọ nìkan, Jèhófà, ló ń mú kí n máa gbé láìséwu.+ Òwe 3:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Nígbà tí o bá dùbúlẹ̀, ẹ̀rù ò ní bà ọ́;+Wàá sùn, oorun rẹ á sì dùn mọ́ ọ.+