ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jeremáyà 12:13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Wọ́n ti gbin àlìkámà,* àmọ́ ẹ̀gún ni wọ́n kórè.+

      Wọ́n ti ṣiṣẹ́ bí ẹní-máa-kú, àmọ́ wọn ò jèrè nǹkan kan.

      Irè oko wọn á dójú tì wọ́n

      Nítorí ìbínú Jèhófà tó ń jó fòfò.”

  • Hágáì 1:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 6 Ẹ ti fún irúgbìn tó pọ̀, àmọ́ irè oko díẹ̀ ni ẹ kó.+ Ẹ̀ ń jẹun, àmọ́ ẹ ò yó. Ẹ̀ ń mu, àmọ́ kò tẹ́ yín lọ́rùn. Ẹ̀ ń wọṣọ, àmọ́ ara ẹnì kankan yín ò móoru. Inú ajádìí àpò ni ẹni tí wọ́n gbà síṣẹ́ ń kó owó iṣẹ́ rẹ̀ sí.’”

  • Hágáì 1:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Torí náà, ọ̀run ò sẹ ìrì, ilẹ̀ ò sì mú èso jáde.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́