-
Àìsáyà 9:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 Ẹnì kan máa gé nǹkan lulẹ̀ ní ọwọ́ ọ̀tún,
Àmọ́ ebi á ṣì máa pa á;
Ẹnì kan sì máa jẹun ní ọwọ́ òsì,
Àmọ́ kò ní yó.
Kálukú máa jẹ ẹran apá rẹ̀,
-
Míkà 6:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Wàá jẹun àmọ́ o ò ní yó,
Inú rẹ máa ṣófo.+
Tí o bá tiẹ̀ rí nǹkan kó, o ò ní lè kó o lọ,
Tí o bá sì rí i kó lọ, màá fi í fún idà.
-
-
-