ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Kíróníkà 34:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Ní ọdún kẹjọ ìjọba rẹ̀, nígbà tó ṣì jẹ́ ọ̀dọ́kùnrin, ó bẹ̀rẹ̀ sí í wá Ọlọ́run Dáfídì baba ńlá rẹ̀;+ ní ọdún kejìlá, ó bẹ̀rẹ̀ sí í mú àwọn ibi gíga+ àti àwọn òpó òrìṣà* àti àwọn ère gbígbẹ́+ pẹ̀lú àwọn ère onírin* kúrò ní Júdà àti Jerúsálẹ́mù.+

  • Àìsáyà 27:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  9 Torí náà, báyìí la ṣe máa ṣètùtù fún ẹ̀ṣẹ̀ Jékọ́bù,+

      Èyí sì ni ohun tó máa jèrè lẹ́kùn-ún rẹ́rẹ́ nígbà tí a bá mú ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀ kúrò:

      Ó máa ṣe gbogbo òkúta pẹpẹ

      Bí òkúta ẹfun tí wọ́n lọ̀ lúúlúú,

      Òpó òrìṣà* àti pẹpẹ tùràrí kankan ò sì ní ṣẹ́ kù.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́