Sáàmù 78:58, 59 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 58 Wọ́n ń fi àwọn ibi gíga wọn mú un bínú ṣáá,+Wọ́n sì fi àwọn ère gbígbẹ́ wọn mú kí ìbínú rẹ̀ ru.*+ 59 Ọlọ́run gbọ́, inú sì bí i gidigidi,+Torí náà, ó kọ Ísírẹ́lì sílẹ̀ pátápátá.
58 Wọ́n ń fi àwọn ibi gíga wọn mú un bínú ṣáá,+Wọ́n sì fi àwọn ère gbígbẹ́ wọn mú kí ìbínú rẹ̀ ru.*+ 59 Ọlọ́run gbọ́, inú sì bí i gidigidi,+Torí náà, ó kọ Ísírẹ́lì sílẹ̀ pátápátá.