ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Àwọn Ọba 25:9, 10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 Ó dáná sun ilé Jèhófà+ àti ilé* ọba+ pẹ̀lú gbogbo ilé tó wà ní Jerúsálẹ́mù;+ ó tún sun ilé gbogbo àwọn ẹni ńlá.+ 10 Gbogbo ògiri tó yí Jerúsálẹ́mù ká ni gbogbo àwọn ọmọ ogun Kálídíà tó wà pẹ̀lú olórí ẹ̀ṣọ́ wó lulẹ̀.+

  • 2 Kíróníkà 36:17
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 Nítorí náà, ó gbé ọba àwọn ará Kálídíà+ dìde sí wọn, ẹni tó fi idà pa àwọn ọ̀dọ́kùnrin wọn+ nínú ibi mímọ́ wọn;+ kò ṣàánú ọ̀dọ́kùnrin tàbí ọ̀dọ́bìnrin,* arúgbó tàbí aláàárẹ̀.+ Ohun gbogbo ni Ọlọ́run fi lé e lọ́wọ́.+

  • Nehemáyà 2:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Nígbà náà, mo sọ fún ọba pé: “Kí ẹ̀mí ọba ó gùn! Báwo ni ojú mi ò ṣe ní fà ro nígbà tí ìlú tí wọ́n sin àwọn baba ńlá mi sí ti di àwókù, tí iná sì ti jó àwọn ẹnubodè rẹ̀?”+

  • Àìsáyà 1:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  7 Ilẹ̀ yín ti di ahoro.

      Wọ́n ti dáná sun àwọn ìlú yín.

      Àwọn àjèjì jẹ ilẹ̀ yín run níṣojú yín.+

      Ó dà bí ilẹ̀ tó di ahoro tí àwọn àjèjì gbà.+

  • Jeremáyà 4:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  7 Ó yọ jáde láti inú igbó bíi kìnnìún;+

      Ẹni tó ń pa àwọn orílẹ̀-èdè run ti jáde.+

      Ó ti jáde kúrò ní àyè rẹ̀ kí ó lè sọ ilẹ̀ rẹ di ohun àríbẹ̀rù.

      Àwọn ìlú rẹ yóò di àwókù tí kò ní sí ẹni tó ń gbé ibẹ̀ mọ́.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́