-
Léfítíkù 25:25Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
25 “‘Tí arákùnrin rẹ bá di aláìní, tó sì tà lára ohun ìní rẹ̀, kí olùtúnrà tó bá a tan tímọ́tímọ́ wá ra ohun tí arákùnrin rẹ̀ tà pa dà.+
-