-
Léfítíkù 4:26Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
26 Kó mú kí gbogbo ọ̀rá rẹ̀ rú èéfín lórí pẹpẹ bí ọ̀rá ẹbọ ìrẹ́pọ̀;+ àlùfáà yóò sì ṣe ètùtù fún un torí ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀, yóò sì rí ìdáríjì.
-