Jẹ́nẹ́sísì 41:52 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 52 Ó sì sọ èkejì ní Éfúrémù,*+ torí ó sọ pé, “Ọlọ́run ti mú kí n di púpọ̀ ní ilẹ̀ tí mo ti jìyà.”+