Hébérù 3:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Bákan náà, àwọn wo ni ọ̀rọ̀ wọn kó Ọlọ́run nírìíra fún ogójì (40) ọdún?+ Ṣebí àwọn tó dẹ́ṣẹ̀, tí òkú wọn sùn nínú aginjù ni?+
17 Bákan náà, àwọn wo ni ọ̀rọ̀ wọn kó Ọlọ́run nírìíra fún ogójì (40) ọdún?+ Ṣebí àwọn tó dẹ́ṣẹ̀, tí òkú wọn sùn nínú aginjù ni?+