ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Nọ́ńbà 14:22, 23
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 22 Síbẹ̀, kò sí ìkankan nínú àwọn tó fojú rí ògo mi àti àwọn iṣẹ́ àmì+ mi tí mo ṣe ní Íjíbítì àti ní aginjù, tó tún wá ń dán mi wò+ nígbà mẹ́wàá yìí, tí kò sì fetí sí ohùn mi,+ 23 tó máa rí ilẹ̀ tí mo búra pé màá fún àwọn bàbá wọn. Àní, ìkankan nínú àwọn tó ń fojú di mí kò ní rí ilẹ̀ náà.+

  • Nọ́ńbà 14:28-30
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 28 Sọ fún wọn pé, ‘“Ó dájú pé bí mo ti wà láàyè,” ni Jèhófà wí, “ohun tí mo gbọ́ tí ẹ sọ+ gẹ́lẹ́ ni màá ṣe sí yín! 29 Inú aginjù yìí lẹ máa kú sí,+ àní gbogbo àwọn tó jẹ́ ẹni ogún (20) ọdún sókè nínú yín, àwọn tí wọ́n forúkọ wọn sílẹ̀, gbogbo ẹ̀yin tí ẹ kùn sí mi.+ 30 Ìkankan nínú yín kò ní wọ ilẹ̀ tí mo búra* pé ẹ máa gbé,+ àfi Kélẹ́bù ọmọ Jéfúnè àti Jóṣúà ọmọ Núnì.+

  • Júùdù 5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 Bó tilẹ̀ jẹ́ pé ẹ mọ gbogbo èyí, mo fẹ́ rán yín létí pé lẹ́yìn tí Jèhófà* ti gba àwọn èèyàn kan là kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì,+ ó pa àwọn tí kò ní ìgbàgbọ́ run.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́