ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 6:16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 Orúkọ àwọn ọmọ Léfì+ nìyí, gẹ́gẹ́ bí ìlà ìdílé wọn: Gẹ́ṣónì, Kóhátì àti Mérárì.+ Ọjọ́ ayé Léfì jẹ́ ọdún mẹ́tàdínlógóje (137).

  • Nọ́ńbà 26:57
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 57 Èyí ni àwọn tí wọ́n forúkọ wọn sílẹ̀ nínú àwọn ọmọ Léfì+ ní ìdílé-ìdílé: látọ̀dọ̀ Gẹ́ṣónì, ìdílé àwọn ọmọ Gẹ́ṣónì; látọ̀dọ̀ Kóhátì,+ ìdílé àwọn ọmọ Kóhátì; látọ̀dọ̀ Mérárì, ìdílé àwọn ọmọ Mérárì.

  • 1 Kíróníkà 23:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 6 Lẹ́yìn náà, Dáfídì ṣètò* wọn sí àwùjọ-àwùjọ+ gẹ́gẹ́ bí àwọn ọmọ Léfì ṣe wà: Gẹ́ṣónì, Kóhátì àti Mérárì.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́