1 Kíróníkà 6:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Àwọn ọmọ* Mérárì ni Máhílì,+ ọmọ rẹ̀ ni Líbínì, ọmọ rẹ̀ ni Ṣíméì, ọmọ rẹ̀ ni Úsà,