Léfítíkù 23:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 “Sọ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé, ‘Àwọn àjọyọ̀ àtìgbàdégbà+ tó jẹ́ ti Jèhófà tí ẹ máa kéde+ jẹ́ àpéjọ mímọ́. Èyí ni àwọn àjọyọ̀ mi àtìgbàdégbà: Diutarónómì 16:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 “Kí gbogbo ọkùnrin rẹ máa fara hàn níwájú Jèhófà Ọlọ́run lẹ́ẹ̀mẹta lọ́dún ní ibi tó bá yàn: ní Àjọyọ̀ Búrẹ́dì Aláìwú,+ Àjọyọ̀ Àwọn Ọ̀sẹ̀+ àti Àjọyọ̀ Àtíbàbà,+ kí ẹnì kankan nínú wọn má sì wá síwájú Jèhófà lọ́wọ́ òfo.
2 “Sọ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé, ‘Àwọn àjọyọ̀ àtìgbàdégbà+ tó jẹ́ ti Jèhófà tí ẹ máa kéde+ jẹ́ àpéjọ mímọ́. Èyí ni àwọn àjọyọ̀ mi àtìgbàdégbà:
16 “Kí gbogbo ọkùnrin rẹ máa fara hàn níwájú Jèhófà Ọlọ́run lẹ́ẹ̀mẹta lọ́dún ní ibi tó bá yàn: ní Àjọyọ̀ Búrẹ́dì Aláìwú,+ Àjọyọ̀ Àwọn Ọ̀sẹ̀+ àti Àjọyọ̀ Àtíbàbà,+ kí ẹnì kankan nínú wọn má sì wá síwájú Jèhófà lọ́wọ́ òfo.