-
Nọ́ńbà 4:38-40Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
38 Wọ́n forúkọ àwọn ọmọ Gẹ́ṣónì+ sílẹ̀ ní ìdílé-ìdílé àti agbo ilé bàbá wọn, 39 gbogbo àwọn tó jẹ́ ẹni ọgbọ̀n (30) ọdún sí àádọ́ta (50) ọdún, tí wọ́n wà lára àwọn tí a yàn pé kí wọ́n máa ṣiṣẹ́ nínú àgọ́ ìpàdé. 40 Gbogbo àwọn tí wọ́n forúkọ wọn sílẹ̀ ní ìdílé-ìdílé àti agbo ilé bàbá wọn jẹ́ ẹgbẹ̀rún méjì ó lé ọgọ́rùn-ún mẹ́fà àti ọgbọ̀n (2,630).+
-