Nọ́ńbà 3:21, 22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Ọ̀dọ̀ Gẹ́ṣónì ni ìdílé àwọn ọmọ Líbínì+ àti ìdílé àwọn ọmọ Ṣíméì ti ṣẹ̀ wá. Ìwọ̀nyí ni ìdílé àwọn ọmọ Gẹ́ṣónì. 22 Gbogbo ọkùnrin tó jẹ́ ọmọ oṣù kan sókè tí wọ́n forúkọ wọn sílẹ̀ jẹ́ ẹgbẹ̀rún méje ààbọ̀ (7,500).+
21 Ọ̀dọ̀ Gẹ́ṣónì ni ìdílé àwọn ọmọ Líbínì+ àti ìdílé àwọn ọmọ Ṣíméì ti ṣẹ̀ wá. Ìwọ̀nyí ni ìdílé àwọn ọmọ Gẹ́ṣónì. 22 Gbogbo ọkùnrin tó jẹ́ ọmọ oṣù kan sókè tí wọ́n forúkọ wọn sílẹ̀ jẹ́ ẹgbẹ̀rún méje ààbọ̀ (7,500).+