Róòmù 7:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Bí àpẹẹrẹ, òfin de obìnrin tí a gbé níyàwó mọ́ ọkọ rẹ̀ nígbà tí ọkùnrin náà bá wà láàyè; àmọ́ tí ọkọ rẹ̀ bá kú, a dá a sílẹ̀ kúrò lábẹ́ òfin ọkọ rẹ̀.+ 1 Kọ́ríńtì 11:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Àmọ́ mo fẹ́ kí ẹ mọ̀ pé orí gbogbo ọkùnrin ni Kristi; + bákan náà, orí obìnrin ni ọkùnrin;+ bákan náà, orí Kristi ni Ọlọ́run.+ Éfésù 5:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Kí àwọn aya máa tẹrí ba fún àwọn ọkọ+ wọn bíi fún Olúwa,
2 Bí àpẹẹrẹ, òfin de obìnrin tí a gbé níyàwó mọ́ ọkọ rẹ̀ nígbà tí ọkùnrin náà bá wà láàyè; àmọ́ tí ọkọ rẹ̀ bá kú, a dá a sílẹ̀ kúrò lábẹ́ òfin ọkọ rẹ̀.+
3 Àmọ́ mo fẹ́ kí ẹ mọ̀ pé orí gbogbo ọkùnrin ni Kristi; + bákan náà, orí obìnrin ni ọkùnrin;+ bákan náà, orí Kristi ni Ọlọ́run.+