Jóṣúà 4:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Àwọn ọmọ Rúbẹ́nì, àwọn ọmọ Gádì àti ààbọ̀ ẹ̀yà Mánásè sọdá ṣáájú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì yòókù, wọ́n tò lọ́wọ̀ọ̀wọ́ láti jagun,+ bí Mósè ṣe pa á láṣẹ fún wọn.+
12 Àwọn ọmọ Rúbẹ́nì, àwọn ọmọ Gádì àti ààbọ̀ ẹ̀yà Mánásè sọdá ṣáájú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì yòókù, wọ́n tò lọ́wọ̀ọ̀wọ́ láti jagun,+ bí Mósè ṣe pa á láṣẹ fún wọn.+