20Ní oṣù kìíní, gbogbo àpéjọ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì dé aginjù Síínì, àwọn èèyàn náà sì bẹ̀rẹ̀ sí í gbé ní Kádéṣì.+ Ibẹ̀ ni Míríámù+ kú sí, ibẹ̀ sì ni wọ́n sin ín sí.
14 torí nígbà tí àpéjọ náà ń bá mi jà ní aginjù Síínì, ẹ ṣe ohun tó lòdì sí àṣẹ tí mo pa pé kí ẹ tipasẹ̀ omi+ náà fi hàn pé mo jẹ́ mímọ́ níṣojú wọn. Èyí ni omi Mẹ́ríbà+ tó wà ní Kádéṣì + ní aginjù Síínì.”+
51 torí pé ẹ̀yin méjèèjì kò jẹ́ olóòótọ́ sí mi láàárín àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, níbi omi Mẹ́ríbà+ ti Kádéṣì ní aginjù Síínì, torí pé ẹ ò fi hàn pé mo jẹ́ mímọ́ lójú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.+