Nọ́ńbà 27:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Jèhófà wá sọ fún Mósè pé: “Gun orí òkè Ábárímù+ yìí, kí o sì wo ilẹ̀ tí màá fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.+ Diutarónómì 32:48, 49 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 48 Jèhófà bá Mósè sọ̀rọ̀ ní ọjọ́ yìí kan náà pé: 49 “Gun òkè Ábárímù+ yìí lọ, Òkè Nébò,+ tó wà ní ilẹ̀ Móábù, tó dojú kọ Jẹ́ríkò, kí o sì wo ilẹ̀ Kénáánì, tí mo fẹ́ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé kó di tiwọn.+
12 Jèhófà wá sọ fún Mósè pé: “Gun orí òkè Ábárímù+ yìí, kí o sì wo ilẹ̀ tí màá fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.+
48 Jèhófà bá Mósè sọ̀rọ̀ ní ọjọ́ yìí kan náà pé: 49 “Gun òkè Ábárímù+ yìí lọ, Òkè Nébò,+ tó wà ní ilẹ̀ Móábù, tó dojú kọ Jẹ́ríkò, kí o sì wo ilẹ̀ Kénáánì, tí mo fẹ́ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé kó di tiwọn.+