Nọ́ńbà 33:47 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 47 Wọ́n wá kúrò ní Alimoni-díbílátáímù, wọ́n sì pàgọ́ sí àwọn òkè Ábárímù+ níwájú Nébò.+ Diutarónómì 32:48, 49 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 48 Jèhófà bá Mósè sọ̀rọ̀ ní ọjọ́ yìí kan náà pé: 49 “Gun òkè Ábárímù+ yìí lọ, Òkè Nébò,+ tó wà ní ilẹ̀ Móábù, tó dojú kọ Jẹ́ríkò, kí o sì wo ilẹ̀ Kénáánì, tí mo fẹ́ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé kó di tiwọn.+
48 Jèhófà bá Mósè sọ̀rọ̀ ní ọjọ́ yìí kan náà pé: 49 “Gun òkè Ábárímù+ yìí lọ, Òkè Nébò,+ tó wà ní ilẹ̀ Móábù, tó dojú kọ Jẹ́ríkò, kí o sì wo ilẹ̀ Kénáánì, tí mo fẹ́ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé kó di tiwọn.+