Diutarónómì 34:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 34 Mósè wá kúrò ní aṣálẹ̀ tó tẹ́jú ní Móábù lọ sí Òkè Nébò,+ sí orí Písígà,+ tó dojú kọ Jẹ́ríkò.+ Jèhófà sì fi gbogbo ilẹ̀ náà hàn án, láti Gílíádì títí dé Dánì+
34 Mósè wá kúrò ní aṣálẹ̀ tó tẹ́jú ní Móábù lọ sí Òkè Nébò,+ sí orí Písígà,+ tó dojú kọ Jẹ́ríkò.+ Jèhófà sì fi gbogbo ilẹ̀ náà hàn án, láti Gílíádì títí dé Dánì+