Diutarónómì 3:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Gun orí Písígà lọ,+ kí o wo ìwọ̀ oòrùn, àríwá, gúúsù àti ìlà oòrùn, kí o sì fi ojú ara rẹ rí ilẹ̀ náà, torí pé o ò ní sọdá Jọ́dánì yìí.+
27 Gun orí Písígà lọ,+ kí o wo ìwọ̀ oòrùn, àríwá, gúúsù àti ìlà oòrùn, kí o sì fi ojú ara rẹ rí ilẹ̀ náà, torí pé o ò ní sọdá Jọ́dánì yìí.+