Jóṣúà 15:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Ilẹ̀ tí wọ́n pín+ fún ẹ̀yà Júdà ní ìdílé-ìdílé lọ dé ààlà Édómù,+ aginjù Síínì, dé ìpẹ̀kun Négébù lápá gúúsù. Jóṣúà 15:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ó sì lọ sápá gúúsù dé ibi tí wọ́n ń gbà gòkè ní Ákírábímù,+ ó dé Síínì, ó gba gúúsù lọ sí Kadeṣi-báníà,+ ó dé Hésírónì, lọ dé Ádáárì, ó sì yí gba ọ̀nà Káríkà.
15 Ilẹ̀ tí wọ́n pín+ fún ẹ̀yà Júdà ní ìdílé-ìdílé lọ dé ààlà Édómù,+ aginjù Síínì, dé ìpẹ̀kun Négébù lápá gúúsù.
3 Ó sì lọ sápá gúúsù dé ibi tí wọ́n ń gbà gòkè ní Ákírábímù,+ ó dé Síínì, ó gba gúúsù lọ sí Kadeṣi-báníà,+ ó dé Hésírónì, lọ dé Ádáárì, ó sì yí gba ọ̀nà Káríkà.