Nọ́ńbà 34:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Kí ààlà yín sì yí gba gúúsù, kó gba ibi tí wọ́n ń gbà gòkè ní Ákírábímù+ títí lọ dé Síínì, kó sì parí sí gúúsù Kadeṣi-báníà.+ Kó wá dé Hasari-ádáárì+ títí lọ dé Ásímónì.
4 Kí ààlà yín sì yí gba gúúsù, kó gba ibi tí wọ́n ń gbà gòkè ní Ákírábímù+ títí lọ dé Síínì, kó sì parí sí gúúsù Kadeṣi-báníà.+ Kó wá dé Hasari-ádáárì+ títí lọ dé Ásímónì.