Nọ́ńbà 13:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Torí náà, wọ́n gòkè lọ, wọ́n sì ṣe amí ilẹ̀ náà láti aginjù Síínì+ dé Réhóbù+ ní tòsí Lebo-hámátì.*+ 2 Àwọn Ọba 14:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Ó gba ààlà ilẹ̀ Ísírẹ́lì pa dà láti Lebo-hámátì*+ títí dé Òkun Árábà,*+ gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ tí Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì gbẹnu ìránṣẹ́ rẹ̀ sọ, ìyẹn Jónà+ ọmọ Ámítáì, wòlíì tó wá láti Gati-héférì.+
21 Torí náà, wọ́n gòkè lọ, wọ́n sì ṣe amí ilẹ̀ náà láti aginjù Síínì+ dé Réhóbù+ ní tòsí Lebo-hámátì.*+
25 Ó gba ààlà ilẹ̀ Ísírẹ́lì pa dà láti Lebo-hámátì*+ títí dé Òkun Árábà,*+ gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ tí Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì gbẹnu ìránṣẹ́ rẹ̀ sọ, ìyẹn Jónà+ ọmọ Ámítáì, wòlíì tó wá láti Gati-héférì.+