-
Nọ́ńbà 3:32Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
32 Olórí ìjòyè àwọn ọmọ Léfì ni Élíásárì+ ọmọ àlùfáà Áárónì, òun ló ń darí àwọn tó ń bójú tó iṣẹ́ ní ibi mímọ́.
-
-
Jóṣúà 14:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Èyí ni ogún tí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì gbà ní ilẹ̀ Kénáánì, èyí tí àlùfáà Élíásárì àti Jóṣúà ọmọ Núnì àtàwọn olórí agbo ilé àwọn ẹ̀yà àwọn ọmọ Ísírẹ́lì fún wọn pé kí wọ́n jogún.+
-