ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Nọ́ńbà 34:18
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 Kí ẹ mú ìjòyè kan látinú ẹ̀yà kọ̀ọ̀kan tó máa pín ilẹ̀ tí ẹ máa jogún+ fún yín.

  • Diutarónómì 32:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  8 Nígbà tí Ẹni Gíga Jù Lọ fún àwọn orílẹ̀-èdè ní ogún+ wọn,

      Nígbà tó ya àwọn ọmọ Ádámù* sọ́tọ̀ọ̀tọ̀,+

      Ó pààlà fún àwọn èèyàn+

      Gẹ́gẹ́ bí iye àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.+

  • Jóṣúà 19:51
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 51 Èyí ni àwọn ogún tí àlùfáà Élíásárì, Jóṣúà ọmọ Núnì àtàwọn olórí agbo ilé bàbá nínú ẹ̀yà àwọn ọmọ Ísírẹ́lì fi kèké pín+ ní Ṣílò+ níwájú Jèhófà, ní ẹnu ọ̀nà àgọ́ ìpàdé.+ Bí wọ́n ṣe pín àwọn ilẹ̀ náà tán nìyẹn.

  • Ìṣe 17:26
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 26 Láti ara ọkùnrin kan ló ti dá+ àwọn èèyàn gbogbo orílẹ̀-èdè láti máa gbé lórí gbogbo ilẹ̀ ayé,+ ó yan àkókò fún àwọn nǹkan, ó sì pa ààlà ibi tí àwọn èèyàn á máa gbé,+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́