-
Diutarónómì 19:8, 9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 “Tí Jèhófà Ọlọ́run rẹ bá mú kí ilẹ̀ rẹ pọ̀ sí i bó ṣe búra fún àwọn baba ńlá rẹ,+ tó sì ti fún ọ ní gbogbo ilẹ̀ tó ṣèlérí pé òun máa fún àwọn baba ńlá rẹ,+ 9 tí o bá ṣáà ti pa gbogbo àṣẹ yìí tí mò ń fún ọ lónìí mọ́ délẹ̀délẹ̀, pé kí o nífẹ̀ẹ́ Jèhófà Ọlọ́run rẹ, kí o sì máa rìn ní àwọn ọ̀nà rẹ̀ nígbà gbogbo,+ kí o fi ìlú mẹ́ta míì kún àwọn mẹ́ta yìí.+
-