-
Jóṣúà 20:4, 5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Kí ẹni náà sá lọ sí ọ̀kan nínú àwọn ìlú yìí,+ kó dúró sí ẹnubodè ìlú náà,+ kó sì ro ẹjọ́ rẹ̀ ní etí àwọn àgbààgbà ìlú náà. Kí wọ́n wá gbà á sínú ìlú náà, kí wọ́n fún un ní ibì kan, kó sì máa bá wọn gbé. 5 Tí ẹni tó ń gbẹ̀san ẹ̀jẹ̀ bá ń lé e, kí wọ́n má fi apààyàn náà lé e lọ́wọ́, torí ṣe ló ṣèèṣì* pa ẹnì kejì rẹ̀, kò sì kórìíra rẹ̀ tẹ́lẹ̀.+
-