Ẹ́kísódù 29:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 “Kí o mú Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀ wá sí ẹnu ọ̀nà àgọ́ ìpàdé,+ kí o sì fi omi wẹ̀ wọ́n.+ Ẹ́kísódù 29:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 kí o mú òróró àfiyanni,+ kí o sì dà á sí i lórí láti fòróró yàn án.+