Jẹ́nẹ́sísì 9:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Yàtọ̀ sí ìyẹn, èmi yóò béèrè ẹ̀jẹ̀ yín tó jẹ́ ẹ̀mí yín* pa dà. Èmi yóò béèrè lọ́wọ́ gbogbo ohun alààyè; ọwọ́ kálukú ni màá sì ti béèrè ẹ̀mí arákùnrin rẹ̀.+ Ẹ́kísódù 21:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Tí ẹnì kan bá bínú gidigidi sí ọmọnìkejì rẹ̀, tó sì mọ̀ọ́mọ̀ pa á,+ kí ẹ pa onítọ̀hún, ì báà jẹ́ ibi pẹpẹ mi lo ti máa wá mú un.+ Diutarónómì 19:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 O* ò gbọ́dọ̀ káàánú rẹ̀, ṣe ni kí o mú ẹ̀bi ẹ̀jẹ̀ ẹni tí kò mọwọ́ mẹsẹ̀ kúrò ní Ísírẹ́lì,+ kí nǹkan lè máa lọ dáadáa fún ọ.
5 Yàtọ̀ sí ìyẹn, èmi yóò béèrè ẹ̀jẹ̀ yín tó jẹ́ ẹ̀mí yín* pa dà. Èmi yóò béèrè lọ́wọ́ gbogbo ohun alààyè; ọwọ́ kálukú ni màá sì ti béèrè ẹ̀mí arákùnrin rẹ̀.+
14 Tí ẹnì kan bá bínú gidigidi sí ọmọnìkejì rẹ̀, tó sì mọ̀ọ́mọ̀ pa á,+ kí ẹ pa onítọ̀hún, ì báà jẹ́ ibi pẹpẹ mi lo ti máa wá mú un.+
13 O* ò gbọ́dọ̀ káàánú rẹ̀, ṣe ni kí o mú ẹ̀bi ẹ̀jẹ̀ ẹni tí kò mọwọ́ mẹsẹ̀ kúrò ní Ísírẹ́lì,+ kí nǹkan lè máa lọ dáadáa fún ọ.