Jẹ́nẹ́sísì 4:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Lẹ́yìn náà, Kéènì sọ fún Ébẹ́lì àbúrò rẹ̀ pé: “Jẹ́ ká lọ sí oko.” Nígbà tí wọ́n sì wà nínú oko, Kéènì lu Ébẹ́lì àbúrò rẹ̀, ó sì pa á.+ Jẹ́nẹ́sísì 4:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ọlọ́run wá sọ pé: “Kí lo ṣe yìí? Tẹ́tí kó o gbọ́ mi! Ẹ̀jẹ̀ àbúrò rẹ ń ké jáde sí mi láti inú ilẹ̀.+ Sáàmù 106:38 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 38 Wọ́n ń ta ẹ̀jẹ̀ aláìṣẹ̀ sílẹ̀,+Ẹ̀jẹ̀ àwọn ọmọkùnrin wọn àti ti àwọn ọmọbìnrin wọnTí wọ́n fi rúbọ sí àwọn òrìṣà Kénáánì;+Ilẹ̀ náà sì di ẹlẹ́gbin nítorí ìtàjẹ̀sílẹ̀. Lúùkù 11:50 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 50 ká lè di ẹ̀bi ẹ̀jẹ̀ gbogbo àwọn wòlíì tí wọ́n ta sílẹ̀ látìgbà ìpìlẹ̀ ayé ru* ìran yìí,+
8 Lẹ́yìn náà, Kéènì sọ fún Ébẹ́lì àbúrò rẹ̀ pé: “Jẹ́ ká lọ sí oko.” Nígbà tí wọ́n sì wà nínú oko, Kéènì lu Ébẹ́lì àbúrò rẹ̀, ó sì pa á.+
10 Ọlọ́run wá sọ pé: “Kí lo ṣe yìí? Tẹ́tí kó o gbọ́ mi! Ẹ̀jẹ̀ àbúrò rẹ ń ké jáde sí mi láti inú ilẹ̀.+
38 Wọ́n ń ta ẹ̀jẹ̀ aláìṣẹ̀ sílẹ̀,+Ẹ̀jẹ̀ àwọn ọmọkùnrin wọn àti ti àwọn ọmọbìnrin wọnTí wọ́n fi rúbọ sí àwọn òrìṣà Kénáánì;+Ilẹ̀ náà sì di ẹlẹ́gbin nítorí ìtàjẹ̀sílẹ̀.