Ìsíkíẹ́lì 16:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 “‘O fi àwọn ọmọ rẹ ọkùnrin àti ọmọ rẹ obìnrin tí o bí fún mi+ rúbọ sí àwọn òrìṣà.+ Ṣé ohun kékeré lo pe iṣẹ́ aṣẹ́wó tí ò ń ṣe ni?
20 “‘O fi àwọn ọmọ rẹ ọkùnrin àti ọmọ rẹ obìnrin tí o bí fún mi+ rúbọ sí àwọn òrìṣà.+ Ṣé ohun kékeré lo pe iṣẹ́ aṣẹ́wó tí ò ń ṣe ni?