Nọ́ńbà 3:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Àwọn ọmọ Mérárì gẹ́gẹ́ bí ìdílé wọn ni Máhílì+ àti Múṣì.+ Ìdílé àwọn ọmọ Léfì nìyí, gẹ́gẹ́ bí agbo ilé bàbá wọn. Nọ́ńbà 26:58 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 58 Àwọn ìdílé àwọn ọmọ Léfì nìyí: ìdílé àwọn ọmọ Líbínì,+ ìdílé àwọn ọmọ Hébúrónì,+ ìdílé àwọn ọmọ Máhílì,+ ìdílé àwọn ọmọ Múṣì,+ ìdílé àwọn ọmọ Kórà. Kóhátì+ bí Ámúrámù.+
20 Àwọn ọmọ Mérárì gẹ́gẹ́ bí ìdílé wọn ni Máhílì+ àti Múṣì.+ Ìdílé àwọn ọmọ Léfì nìyí, gẹ́gẹ́ bí agbo ilé bàbá wọn.
58 Àwọn ìdílé àwọn ọmọ Léfì nìyí: ìdílé àwọn ọmọ Líbínì,+ ìdílé àwọn ọmọ Hébúrónì,+ ìdílé àwọn ọmọ Máhílì,+ ìdílé àwọn ọmọ Múṣì,+ ìdílé àwọn ọmọ Kórà. Kóhátì+ bí Ámúrámù.+