Léfítíkù 25:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Kí ẹ ya ọdún àádọ́ta (50) sí mímọ́, kí ẹ sì kéde òmìnira fún gbogbo àwọn tó ń gbé ilẹ̀ náà.+ Yóò di Júbílì fún yín, kálukú yín á pa dà sídìí ohun ìní rẹ̀, kálukú yín á sì pa dà sọ́dọ̀ ìdílé rẹ̀.+
10 Kí ẹ ya ọdún àádọ́ta (50) sí mímọ́, kí ẹ sì kéde òmìnira fún gbogbo àwọn tó ń gbé ilẹ̀ náà.+ Yóò di Júbílì fún yín, kálukú yín á pa dà sídìí ohun ìní rẹ̀, kálukú yín á sì pa dà sọ́dọ̀ ìdílé rẹ̀.+