-
Nọ́ńbà 4:42-44Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
42 Wọ́n forúkọ àwọn ọmọ Mérárì sílẹ̀ ní ìdílé-ìdílé àti agbo ilé bàbá wọn, 43 gbogbo àwọn tó jẹ́ ẹni ọgbọ̀n (30) ọdún sí àádọ́ta (50) ọdún, tí wọ́n wà lára àwọn tí a yàn pé kí wọ́n máa ṣiṣẹ́ nínú àgọ́ ìpàdé.+ 44 Gbogbo àwọn tí wọ́n forúkọ wọn sílẹ̀ ní ìdílé-ìdílé jẹ́ ẹgbẹ̀rún mẹ́ta ó lé igba (3,200).+
-