Nọ́ńbà 3:33, 34 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 Látọ̀dọ̀ Mérárì ni ìdílé àwọn ọmọ Máhílì àti ìdílé àwọn ọmọ Múṣì ti ṣẹ̀ wá. Ìwọ̀nyí ni àwọn ìdílé Mérárì.+ 34 Gbogbo ọkùnrin tó jẹ́ ọmọ oṣù kan sókè tí wọ́n forúkọ wọn sílẹ̀ jẹ́ ẹgbẹ̀rún mẹ́fà ó lé igba (6,200).+
33 Látọ̀dọ̀ Mérárì ni ìdílé àwọn ọmọ Máhílì àti ìdílé àwọn ọmọ Múṣì ti ṣẹ̀ wá. Ìwọ̀nyí ni àwọn ìdílé Mérárì.+ 34 Gbogbo ọkùnrin tó jẹ́ ọmọ oṣù kan sókè tí wọ́n forúkọ wọn sílẹ̀ jẹ́ ẹgbẹ̀rún mẹ́fà ó lé igba (6,200).+