-
1 Kíróníkà 23:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Wọ́n ka iye+ àwọn ọmọ Léfì láti ẹni ọgbọ̀n (30) ọdún sókè; iye àwọn ọkùnrin tí wọ́n kà lọ́kọ̀ọ̀kan jẹ́ ẹgbẹ̀rún méjìdínlógójì (38,000).
-