ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Mátíù 1:1-17
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 1 Ìwé ìtàn* nípa Jésù Kristi,* ọmọ Dáfídì,+ ọmọ Ábúráhámù:+

       2 Ábúráhámù bí Ísákì;+

      Ísákì bí Jékọ́bù;+

      Jékọ́bù bí Júdà+ àti àwọn arákùnrin rẹ̀;

       3 Támárì bí Pérésì àti Síírà+ fún Júdà;

      Pérésì bí Hésírónì;+

      Hésírónì bí Rámù;+

       4 Rámù bí Ámínádábù;

      Ámínádábù bí Náṣónì;+

      Náṣónì bí Sálímọ́nì;

       5 Ráhábù+ bí Bóásì fún Sálímọ́nì;

      Rúùtù bí Óbédì fún Bóásì;+

      Óbédì bí Jésè;+

       6 Jésè bí Dáfídì+ ọba.

      Ìyàwó Ùráyà bí Sólómọ́nì+ fún Dáfídì;

       7 Sólómọ́nì bí Rèhóbóámù;+

      Rèhóbóámù bí Ábíjà;

      Ábíjà bí Ásà;+

       8 Ásà bí Jèhóṣáfátì;+

      Jèhóṣáfátì bí Jèhórámù;+

      Jèhórámù bí Ùsáyà;

       9 Ùsáyà bí Jótámù;+

      Jótámù bí Áhásì;+

      Áhásì bí Hẹsikáyà;+

      10 Hẹsikáyà bí Mánásè;+

      Mánásè bí Ámọ́nì;+

      Ámọ́nì bí Jòsáyà;+

      11 Jòsáyà+ bí Jekonáyà+ àti àwọn arákùnrin rẹ̀ nígbà tí wọ́n kó wọn lọ sí Bábílónì.+

      12 Lẹ́yìn tí wọ́n kó wọn lọ sí Bábílónì, Jekonáyà bí Ṣéálítíẹ́lì;

      Ṣéálítíẹ́lì bí Serubábélì;+

      13 Serubábélì bí Ábíúdù;

      Ábíúdù bí Élíákímù;

      Élíákímù bí Ásórì;

      14 Ásórì bí Sádókù;

      Sádókù bí Ákímù;

      Ákímù bí Élíúdù;

      15 Élíúdù bí Élíásárì;

      Élíásárì bí Mátáánì;

      Mátáánì bí Jékọ́bù;

      16 Jékọ́bù bí Jósẹ́fù ọkọ Màríà, ẹni tó bí Jésù,+ tí à ń pè ní Kristi.+

      17 Torí náà, gbogbo ìran náà látọ̀dọ̀ Ábúráhámù dórí Dáfídì jẹ́ ìran mẹ́rìnlá (14); látọ̀dọ̀ Dáfídì di ìgbà tí wọ́n kó wọn lọ sí Bábílónì, ìran mẹ́rìnlá (14); látìgbà tí wọ́n kó wọn lọ sí Bábílónì di ìgbà Kristi, ìran mẹ́rìnlá (14).

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́